Jeremáyà 7:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 “‘Nítorí náà, wò ó! ọjọ́ ń bọ̀,’ ni Jèhófà wí, ‘tí a kò ní pè é ní Tófétì tàbí Àfonífojì Ọmọ Hínómù mọ́,* àmọ́ Àfonífojì Ìpànìyàn la ó máa pè é. Wọ́n á sin òkú ní Tófétì títí kò fi ní sí àyè mọ́.+
32 “‘Nítorí náà, wò ó! ọjọ́ ń bọ̀,’ ni Jèhófà wí, ‘tí a kò ní pè é ní Tófétì tàbí Àfonífojì Ọmọ Hínómù mọ́,* àmọ́ Àfonífojì Ìpànìyàn la ó máa pè é. Wọ́n á sin òkú ní Tófétì títí kò fi ní sí àyè mọ́.+