Jeremáyà 1:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Má ṣe jẹ́ kí ìrísí wọn dẹ́rù bà ọ́,+Nítorí ‘mo wà pẹ̀lú rẹ láti gbà ọ́,’+ ni Jèhófà wí.” Róòmù 8:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Kí ni ká wá sọ sọ́rọ̀ yìí? Tí Ọlọ́run bá wà lẹ́yìn wa, ta ló lè dènà wa?+