ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 23:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 “Ẹ gbé, ẹ̀yin olùṣọ́ àgùntàn tó ń pa àwọn àgùntàn ibi ìjẹko mi run, tí ẹ sì ń tú wọn ká!” ni Jèhófà wí.+

  • Ìsíkíẹ́lì 34:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 “Ọmọ èèyàn, sọ àsọtẹ́lẹ̀ sórí àwọn olùṣọ́ àgùntàn Ísírẹ́lì. Sọ tẹ́lẹ̀, kí o sì sọ fún àwọn olùṣọ́ àgùntàn pé, ‘Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Ẹ gbé, ẹ̀yin olùṣọ́ àgùntàn Ísírẹ́lì,+ tí ẹ̀ ń bọ́ ara yín! Ǹjẹ́ kì í ṣe agbo ẹran ló yẹ kí ẹ̀yin olùṣọ́ àgùntàn máa bọ́?+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́