ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 23:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 “Ẹ gbé, ẹ̀yin olùṣọ́ àgùntàn tó ń pa àwọn àgùntàn ibi ìjẹko mi run, tí ẹ sì ń tú wọn ká!” ni Jèhófà wí.+

  • Míkà 3:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Mo sọ pé: “Ẹ jọ̀ọ́ ẹ gbọ́, ẹ̀yin olórí ilé Jékọ́bù

      Àti ẹ̀yin aláṣẹ ilé Ísírẹ́lì.+

      Ṣé kò yẹ kí ẹ mọ ohun tó tọ́?

  • Míkà 3:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Àwọn olórí* rẹ̀ ń gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ kí wọ́n tó dájọ́,+

      Àwọn àlùfáà rẹ̀ ń gba owó kí wọ́n tó kọ́ni,+

      Àwọn wòlíì rẹ̀ ń gba owó* kí wọ́n tó woṣẹ́.+

      Síbẹ̀ wọ́n gbára lé Jèhófà,* wọ́n ń sọ pé:

      “Ṣebí Jèhófà wà pẹ̀lú wa?+

      Àjálù kankan ò lè dé bá wa.”+

  • Sefanáyà 3:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Àwọn olórí tó wà nínú rẹ̀ jẹ́ kìnnìún tó ń ké ramúramù.+

      Àwọn onídàájọ́ rẹ̀ jẹ́ ìkookò ní alẹ́;

      Wọn kì í jẹ egungun kankan kù di òwúrọ̀.

  • Sekaráyà 11:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 O gbé, ìwọ olùṣọ́ àgùntàn mi tí kò wúlò,+ tó ń pa agbo ẹran tì!+

      Idà yóò ṣá a ní apá àti ojú ọ̀tún rẹ̀.

      Apá rẹ̀ á rọ pátápátá,

      Ojú ọ̀tún rẹ̀ á sì fọ́ yán-án yán-án.”*

  • Mátíù 23:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 “Ẹ gbé, ẹ̀yin akọ̀wé òfin àti Farisí, ẹ̀yin alágàbàgebè! torí pé ẹ ti Ìjọba ọ̀run pa mọ́ àwọn èèyàn; ẹ̀yin fúnra yín ò wọlé, ẹ ò sì jẹ́ kí àwọn tó fẹ́ wọlé ráyè wọlé.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́