Jeremáyà 4:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Nítorí mo gbọ́ ohùn kan tó dà bíi ti obìnrin tó ń ṣàìsàn,Ìdààmú bíi ti obìnrin tó ń rọbí àkọ́bí ọmọ rẹ̀,Ohùn ọmọbìnrin Síónì tó ń mí gúlegúle. Bó ṣe tẹ́ àtẹ́lẹwọ́ rẹ̀, ó ń sọ pé:+ “Mo gbé, àárẹ̀ ti mú mi* nítorí àwọn apààyàn!” Jeremáyà 6:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 A ti gbọ́ ìròyìn nípa rẹ̀. Ọwọ́ wa rọ;+Wàhálà ti bá wa,Ìdààmú* sì bá wa bíi ti obìnrin tó ń rọbí.+
31 Nítorí mo gbọ́ ohùn kan tó dà bíi ti obìnrin tó ń ṣàìsàn,Ìdààmú bíi ti obìnrin tó ń rọbí àkọ́bí ọmọ rẹ̀,Ohùn ọmọbìnrin Síónì tó ń mí gúlegúle. Bó ṣe tẹ́ àtẹ́lẹwọ́ rẹ̀, ó ń sọ pé:+ “Mo gbé, àárẹ̀ ti mú mi* nítorí àwọn apààyàn!”
24 A ti gbọ́ ìròyìn nípa rẹ̀. Ọwọ́ wa rọ;+Wàhálà ti bá wa,Ìdààmú* sì bá wa bíi ti obìnrin tó ń rọbí.+