-
2 Àwọn Ọba 24:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Níkẹyìn, Jèhóákímù sinmi pẹ̀lú àwọn baba ńlá rẹ̀;+ Jèhóákínì ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.
-
-
Jeremáyà 22:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Ṣé ọkùnrin yìí, Konáyà, jẹ́ ẹni ẹ̀sín, ìkòkò tó ti fọ́,
Ohun èlò tí ẹnikẹ́ni kò fẹ́?
Kí nìdí tí a fi wó òun pẹ̀lú àtọmọdọ́mọ rẹ̀ lulẹ̀
Tí a sì sọ wọ́n sí ilẹ̀ tí wọn kò mọ̀?’+
-