ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 50:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Màá mú Ísírẹ́lì pa dà sí ibi ìjẹko rẹ̀,+ á jẹko ní Kámẹ́lì àti ní Báṣánì,+ á* sì ní ìtẹ́lọ́rùn lórí àwọn òkè Éfúrémù+ àti ti Gílíádì.’”+

  • Ìsíkíẹ́lì 34:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Èmi yóò bọ́ wọn ní ibi ìjẹko tó dáa, ilẹ̀ tí wọ́n á sì ti máa jẹko yóò wà lórí àwọn òkè gíga Ísírẹ́lì.+ Wọ́n á dùbúlẹ̀ síbẹ̀, níbi ìjẹko tó dáa,+ orí ilẹ̀ tó sì dáa jù lórí àwọn òkè Ísírẹ́lì ni wọ́n á ti máa jẹ ewéko.”

  • Míkà 2:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Ẹ̀yin ilé Jékọ́bù, èmi yóò kó gbogbo yín jọ;

      Ó dájú pé màá kó àwọn tó ṣẹ́ kù ní Ísírẹ́lì jọ.+

      Màá mú kí wọ́n wà ní ìṣọ̀kan, bí àgùntàn ní ilé ẹran,

      Bí agbo ẹran ní pápá ìjẹko wọn;+

      Ariwo àwọn èèyàn máa gba ibẹ̀ kan.’+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́