Ìdárò 2:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ìran tí àwọn wòlíì rẹ rí fún ọ jẹ́ èké àti asán,+Wọn kò fi àṣìṣe rẹ hàn ọ́ láti gbà ọ́ lọ́wọ́ oko ẹrú,+Ṣùgbọ́n ìran tí wọ́n ń rí, tí wọ́n sì ń kéde fún ọ jẹ́ èké àti ìṣìnà.+
14 Ìran tí àwọn wòlíì rẹ rí fún ọ jẹ́ èké àti asán,+Wọn kò fi àṣìṣe rẹ hàn ọ́ láti gbà ọ́ lọ́wọ́ oko ẹrú,+Ṣùgbọ́n ìran tí wọ́n ń rí, tí wọ́n sì ń kéde fún ọ jẹ́ èké àti ìṣìnà.+