Jeremáyà 12:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “Mo ti pa ilé mi tì,+ mo sì ti pa ogún mi tì.+ Mo ti fa olólùfẹ́ mi ọ̀wọ́n* lé àwọn ọ̀tá rẹ̀ lọ́wọ́.+
7 “Mo ti pa ilé mi tì,+ mo sì ti pa ogún mi tì.+ Mo ti fa olólùfẹ́ mi ọ̀wọ́n* lé àwọn ọ̀tá rẹ̀ lọ́wọ́.+