Jeremáyà 49:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “Édómù á di ohun àríbẹ̀rù.+ Gbogbo ẹni tó bá ń kọjá lọ lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀ á wò ó, ẹ̀rù á bà á, á sì súfèé nítorí gbogbo ìyọnu tó bá Édómù. Ìdárò 4:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Máa yọ̀ kí inú rẹ sì máa dùn, ìwọ ọmọbìnrin Édómù,+ bí o ṣe ń gbé ní ilẹ̀ Úsì. Àmọ́ wọ́n á gbé ife náà fún ìwọ pẹ̀lú,+ wàá mu àmupara, wàá sì tú ara rẹ sí ìhòòhò.+
17 “Édómù á di ohun àríbẹ̀rù.+ Gbogbo ẹni tó bá ń kọjá lọ lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀ á wò ó, ẹ̀rù á bà á, á sì súfèé nítorí gbogbo ìyọnu tó bá Édómù.
21 Máa yọ̀ kí inú rẹ sì máa dùn, ìwọ ọmọbìnrin Édómù,+ bí o ṣe ń gbé ní ilẹ̀ Úsì. Àmọ́ wọ́n á gbé ife náà fún ìwọ pẹ̀lú,+ wàá mu àmupara, wàá sì tú ara rẹ sí ìhòòhò.+