-
Jeremáyà 49:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Ṣùgbọ́n, ṣe ni màá tú Ísọ̀ sí borokoto.
Màá tú àwọn ibi tó ń sá pa mọ́ sí síta,
Kó má lè rí ibi sá pa mọ́ sí mọ́.
-
-
Jeremáyà 49:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Nítorí ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Wò ó! Bí àwọn tí kò jẹ̀bi láti mu ife náà bá ní láti mu ún ní dandan, ṣé ó wá yẹ kí a fi ọ́ sílẹ̀ láìjìyà? A ò ní fi ọ́ sílẹ̀ láìjìyà, nítorí o gbọ́dọ̀ mu ún.”+
-