ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 55:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Kí èèyàn burúkú fi ọ̀nà rẹ̀ sílẹ̀,+

      Kí ẹni ibi sì yí èrò rẹ̀ pa dà;

      Kó pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà, ẹni tó máa ṣàánú rẹ̀,+

      Sọ́dọ̀ Ọlọ́run wa, torí ó máa dárí jini fàlàlà.*+

  • Jeremáyà 18:7, 8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Nígbà tí mo bá sọ pé màá fa orílẹ̀-èdè kan tàbí ìjọba kan tu, tí mo sọ pé màá ya á lulẹ̀, tí màá sì pa á run,+ 8 bí orílẹ̀-èdè náà bá jáwọ́ nínú ìwà burúkú rẹ̀ tí mo kìlọ̀ fún un, èmi náà á pèrò dà* lórí àjálù tí mo ti sọ pé màá jẹ́ kó dé bá a.+

  • Jeremáyà 36:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Bóyá nígbà tí àwọn ará ilé Júdà bá gbọ́ nípa gbogbo àjálù tí mo fẹ́ mú bá wọn, wọ́n á lè yí pa dà kúrò nínú ìwà ibi wọn, kí n sì dárí àṣìṣe wọn àti ẹ̀ṣẹ̀ wọn jì wọ́n.”+

  • Ìsíkíẹ́lì 18:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 “‘Àmọ́ tí ẹni burúkú bá yí pa dà kúrò nínú iṣẹ́ ibi tó ti ṣe, tó sì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe ohun tó tọ́ àti ohun tó jẹ́ òdodo, ó máa dá ẹ̀mí* rẹ̀ sí.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́