2 Kíróníkà 28:20, 21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Níkẹyìn, Tiliga-pílínésà+ ọba Ásíríà wá gbéjà kò ó, ó sì kó ìdààmú bá a+ dípò kó fún un lókun. 21 Áhásì ti kó àwọn nǹkan tó wà ní ilé Jèhófà àti ilé* ọba+ àti ilé àwọn ìjòyè, ó sì fi ṣe ẹ̀bùn fún ọba Ásíríà; àmọ́ kò ṣe é láǹfààní kankan.
20 Níkẹyìn, Tiliga-pílínésà+ ọba Ásíríà wá gbéjà kò ó, ó sì kó ìdààmú bá a+ dípò kó fún un lókun. 21 Áhásì ti kó àwọn nǹkan tó wà ní ilé Jèhófà àti ilé* ọba+ àti ilé àwọn ìjòyè, ó sì fi ṣe ẹ̀bùn fún ọba Ásíríà; àmọ́ kò ṣe é láǹfààní kankan.