2 Kíróníkà 32:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Àmọ́, Hẹsikáyà rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀, ó sì mú ìgbéraga ọkàn rẹ̀ kúrò,+ òun àti àwọn tó ń gbé Jerúsálẹ́mù, ìbínú Jèhófà kò sì wá sórí wọn ní ìgbà ayé Hẹsikáyà.+
26 Àmọ́, Hẹsikáyà rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀, ó sì mú ìgbéraga ọkàn rẹ̀ kúrò,+ òun àti àwọn tó ń gbé Jerúsálẹ́mù, ìbínú Jèhófà kò sì wá sórí wọn ní ìgbà ayé Hẹsikáyà.+