-
Jeremáyà 26:18, 19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 “Míkà+ ti Móréṣétì sọ tẹ́lẹ̀ nígbà ayé Hẹsikáyà+ ọba Júdà, ó sì sọ fún gbogbo èèyàn Júdà pé, ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí:
“Wọ́n á túlẹ̀ Síónì bíi pápá,
Jerúsálẹ́mù á di àwókù,+
19 “Ṣé Ọba Hẹsikáyà ti Júdà àti gbogbo àwọn èèyàn Júdà wá pa á ni? Ǹjẹ́ kò bẹ̀rù Jèhófà, tó sì bẹ Jèhófà pé kó ṣojú rere sí òun,* tí Jèhófà fi pèrò dà* lórí àjálù tó sọ pé òun máa mú bá wọn?+ Nítorí náà, àjálù ńlá ni a fẹ́ fà wá bá ara* wa yìí o.
-