ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 48:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 48 Sí Móábù,+ ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì, sọ nìyí:

      “Nébò gbé! + nítorí wọ́n ti pa á run.

      Ìtìjú ti bá Kiriátáímù,+ wọ́n sì ti gbà á.

      Ìtìjú ti bá ibi ààbò,* wọ́n sì ti wó o lulẹ̀.+

  • Ìsíkíẹ́lì 25:8, 9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 “Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: ‘Torí Móábù+ àti Séírì + sọ pé: “Wò ó! Ilé Júdà dà bíi gbogbo orílẹ̀-èdè yòókù,” 9 èmi yóò mú kó rọrùn láti gbógun ti àwọn ìlú tó wà ní ẹ̀gbẹ́* Móábù, ní ààlà rẹ̀. Àwọn ló rẹwà* jù ní ilẹ̀ náà, Bẹti-jẹ́ṣímótì, Baali-méónì, títí dé Kiriátáímù.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́