-
Àìsáyà 23:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Kí ojú tì ọ́, ìwọ Sídónì, ìwọ ibi ààbò òkun,
Torí òkun ti sọ pé:
-
-
Ìsíkíẹ́lì 28:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 “Ọmọ èèyàn, yíjú rẹ sọ́dọ̀ Sídónì,+ kí o sì sọ àsọtẹ́lẹ̀ sórí rẹ̀.
-
-
Jóẹ́lì 3:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Kí ló dé tí ẹ fi ṣe báyìí sí mi,
Tírè, Sídónì àti gbogbo ilẹ̀ Filísíà?
Ṣé mo ṣẹ̀ yín ni tí ẹ fi ń gbẹ̀san?
Tó bá jẹ́ ẹ̀san lẹ̀ ń gbà,
Ṣe ni màá yára dá a pa dà sórí yín láìjáfara.+
-