-
Jeremáyà 27:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 “‘“‘Àmọ́, orílẹ̀-èdè tó bá fi ọrùn rẹ̀ sábẹ́ àjàgà ọba Bábílónì, tí ó sì sìn ín, ni màá jẹ́ kó dúró* sórí ilẹ̀ rẹ̀,’ ni Jèhófà wí, ‘láti máa ro ó, kí ó sì máa gbé orí rẹ̀.’”’”
-