ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 7:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Ó fi bàbà ṣe kẹ̀kẹ́ ẹrù*+ mẹ́wàá. Gígùn kẹ̀kẹ́ ẹrù kọ̀ọ̀kan jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́rin, fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́rin, gíga rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́ta.

  • 2 Àwọn Ọba 25:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Ní ti àwọn òpó méjèèjì àti Òkun pẹ̀lú àwọn kẹ̀kẹ́ ẹrù tí Sólómọ́nì ṣe fún ilé Jèhófà, bàbà tó wà lára gbogbo àwọn nǹkan èlò yìí kọjá wíwọ̀n.+

  • 2 Kíróníkà 4:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Hírámù tún ṣe àwọn garawa, àwọn ṣọ́bìrì àti àwọn abọ́.+

      Bẹ́ẹ̀ ni Hírámù parí iṣẹ́ tó ṣe fún Ọba Sólómọ́nì ní ilé Ọlọ́run tòótọ́, ìyẹn:+

  • 2 Kíróníkà 4:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 kẹ̀kẹ́ ẹrù* mẹ́wẹ̀ẹ̀wá àti bàsíà mẹ́wẹ̀ẹ̀wá tó wà lórí àwọn kẹ̀kẹ́ ẹrù náà;+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́