2 Àwọn Ọba 24:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ọba Bábílónì fi Matanáyà àbúrò bàbá Jèhóákínì+ jọba ní ipò rẹ̀, ó sì yí orúkọ rẹ̀ pa dà sí Sedekáyà.+ 2 Kíróníkà 36:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún,* Ọba Nebukadinésárì ní kí wọ́n lọ mú un wá sí Bábílónì+ pẹ̀lú àwọn ohun iyebíye tó wà ní ilé Jèhófà.+ Bákan náà, ó fi Sedekáyà arákùnrin bàbá rẹ̀ jọba lórí Júdà àti Jerúsálẹ́mù.+
17 Ọba Bábílónì fi Matanáyà àbúrò bàbá Jèhóákínì+ jọba ní ipò rẹ̀, ó sì yí orúkọ rẹ̀ pa dà sí Sedekáyà.+
10 Ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún,* Ọba Nebukadinésárì ní kí wọ́n lọ mú un wá sí Bábílónì+ pẹ̀lú àwọn ohun iyebíye tó wà ní ilé Jèhófà.+ Bákan náà, ó fi Sedekáyà arákùnrin bàbá rẹ̀ jọba lórí Júdà àti Jerúsálẹ́mù.+