ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 27:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Ní kí wọ́n sọ fún ọ̀gá wọn, pé:

      “‘“Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí, ohun tí ẹ ó sọ fún àwọn ọ̀gá yín rèé,

  • Jeremáyà 27:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 “‘“‘Tí orílẹ̀-èdè tàbí ìjọba èyíkéyìí bá kọ̀ láti sin Ọba Nebukadinésárì ti Bábílónì, tí kò sì fi ọrùn rẹ̀ sábẹ́ àjàgà ọba Bábílónì, ńṣe ni màá fìyà jẹ orílẹ̀-èdè yẹn nípa idà,+ ìyàn àti àjàkálẹ̀ àrùn,’* ni Jèhófà wí, ‘títí màá fi run wọ́n láti ọwọ́ rẹ̀.’

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́