Jóẹ́lì 2:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Jèhófà yóò gbé ohùn sókè níwájú àwọn ọmọ ogun rẹ̀,+ torí wọ́n pọ̀ gan-an nínú ibùdó rẹ̀.+ Alágbára ni ẹni tó ń mú ọ̀rọ̀ Rẹ̀ ṣẹ;Torí ọjọ́ ńlá ni ọjọ́ Jèhófà, ó sì ń bani lẹ́rù.+ Ta ló lè fara dà á?”+ Sefanáyà 1:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ọjọ́ ńlá Jèhófà sún mọ́lé!+ Ó sún mọ́lé, ó sì ń yára bọ̀ kánkán!*+ Ìró ọjọ́ Jèhófà korò.+ Akíkanjú ológun máa figbe ta níbẹ̀.+
11 Jèhófà yóò gbé ohùn sókè níwájú àwọn ọmọ ogun rẹ̀,+ torí wọ́n pọ̀ gan-an nínú ibùdó rẹ̀.+ Alágbára ni ẹni tó ń mú ọ̀rọ̀ Rẹ̀ ṣẹ;Torí ọjọ́ ńlá ni ọjọ́ Jèhófà, ó sì ń bani lẹ́rù.+ Ta ló lè fara dà á?”+
14 Ọjọ́ ńlá Jèhófà sún mọ́lé!+ Ó sún mọ́lé, ó sì ń yára bọ̀ kánkán!*+ Ìró ọjọ́ Jèhófà korò.+ Akíkanjú ológun máa figbe ta níbẹ̀.+