Jeremáyà 30:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó mà ṣe o! Nítorí ọjọ́ burúkú* ni ọjọ́ yẹn máa jẹ́.+ Kò sí irú rẹ̀,Àkókò wàhálà ni fún Jékọ́bù. Ṣùgbọ́n a ó gbà á là.” Émọ́sì 5:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 ‘Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń fẹ́ kí ọjọ́ Jèhófà dé, ẹ gbé!+ Àǹfààní wo wá ni ọjọ́ Jèhófà máa ṣe yín?+ Òkùnkùn ló máa jẹ́, kì í ṣe ìmọ́lẹ̀.+ Sefanáyà 1:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ọjọ́ yẹn jẹ́ ọjọ́ ìbínú ńlá,+Ọjọ́ wàhálà àti ìdààmú,+Ọjọ́ ìjì àti ìsọdahoro,Ọjọ́ òkùnkùn àti ìṣúdùdù,+Ọjọ́ ìkùukùu* àti ìṣúdùdù tó kàmàmà,+
7 Ó mà ṣe o! Nítorí ọjọ́ burúkú* ni ọjọ́ yẹn máa jẹ́.+ Kò sí irú rẹ̀,Àkókò wàhálà ni fún Jékọ́bù. Ṣùgbọ́n a ó gbà á là.”
18 ‘Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń fẹ́ kí ọjọ́ Jèhófà dé, ẹ gbé!+ Àǹfààní wo wá ni ọjọ́ Jèhófà máa ṣe yín?+ Òkùnkùn ló máa jẹ́, kì í ṣe ìmọ́lẹ̀.+
15 Ọjọ́ yẹn jẹ́ ọjọ́ ìbínú ńlá,+Ọjọ́ wàhálà àti ìdààmú,+Ọjọ́ ìjì àti ìsọdahoro,Ọjọ́ òkùnkùn àti ìṣúdùdù,+Ọjọ́ ìkùukùu* àti ìṣúdùdù tó kàmàmà,+