- 
	                        
            
            Àìsáyà 49:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        26 Màá mú kí àwọn tó ń fìyà jẹ ọ́ jẹ ẹran ara tiwọn, Wọ́n sì máa mu ẹ̀jẹ̀ ara wọn yó bí ẹni mu wáìnì tó dùn. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Jeremáyà 50:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        18 Nítorí náà, ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí: ‘Wò ó, màá fìyà jẹ ọba Bábílónì àti ilẹ̀ rẹ̀ bí mo ṣe fìyà jẹ ọba Ásíríà.+ 
 
-