Jeremáyà 33:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Màá mú àwọn ará Júdà àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó wà lóko ẹrú pa dà,+ màá sì fún wọn lókun bí mo ti ṣe ní ìbẹ̀rẹ̀.+ Émọ́sì 9:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 ‘Ní ọjọ́ yẹn, màá gbé àtíbàbà* Dáfídì+ tó ti wó dìde,Màá sì tún àwọn àlàfo rẹ̀* ṣe,Màá tún àwókù rẹ̀ kọ́;Màá tún un kọ́, á sì rí bíi ti tẹ́lẹ̀,+
7 Màá mú àwọn ará Júdà àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó wà lóko ẹrú pa dà,+ màá sì fún wọn lókun bí mo ti ṣe ní ìbẹ̀rẹ̀.+
11 ‘Ní ọjọ́ yẹn, màá gbé àtíbàbà* Dáfídì+ tó ti wó dìde,Màá sì tún àwọn àlàfo rẹ̀* ṣe,Màá tún àwókù rẹ̀ kọ́;Màá tún un kọ́, á sì rí bíi ti tẹ́lẹ̀,+