- 
	                        
            
            Ìsíkíẹ́lì 23:4, 5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        4 Orúkọ ẹ̀gbọ́n ni Òhólà,* orúkọ àbúrò rẹ̀ sì ni Òhólíbà.* Wọ́n di tèmi, wọ́n sì bí àwọn ọmọ ọkùnrin àti obìnrin. Èyí tó ń jẹ́ Òhólà ni Samáríà,+ èyí tó sì ń jẹ́ Òhólíbà ni Jerúsálẹ́mù. 5 “Nígbà tí Òhólà ṣì jẹ́ tèmi, ó bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe aṣẹ́wó.+ Ọkàn rẹ̀ fà sí àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ àtàtà,+ àwọn ará Ásíríà tó jẹ́ aládùúgbò rẹ̀ kó lè bá wọn ṣèṣekúṣe.+ 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Ìsíkíẹ́lì 23:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        9 Torí náà, mo mú kí ọwọ́ àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ àtàtà tẹ̀ ẹ́, àwọn ọmọ Ásíríà+ tí ọkàn rẹ̀ fà sí. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Hósíà 2:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        Kí ó jáwọ́ nínú ìṣekúṣe* rẹ̀ Kí ó sì mú ìwà àgbèrè kúrò láàárín ọmú rẹ̀, 
 
-