Jeremáyà 3:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Nígbà tí mo rí ìyẹn, mo lé Ísírẹ́lì aláìṣòótọ́ lọ, mo sì já ìwé ẹ̀rí ìkọ̀sílẹ̀+ fún un nítorí àgbèrè rẹ̀.+ Síbẹ̀, ẹ̀rù kò ba Júdà arábìnrin rẹ̀ tó ń ṣe békebèke; ṣe ni òun náà tún lọ ṣe iṣẹ́ aṣẹ́wó.+
8 Nígbà tí mo rí ìyẹn, mo lé Ísírẹ́lì aláìṣòótọ́ lọ, mo sì já ìwé ẹ̀rí ìkọ̀sílẹ̀+ fún un nítorí àgbèrè rẹ̀.+ Síbẹ̀, ẹ̀rù kò ba Júdà arábìnrin rẹ̀ tó ń ṣe békebèke; ṣe ni òun náà tún lọ ṣe iṣẹ́ aṣẹ́wó.+