- 
	                        
            
            Jẹ́nẹ́sísì 48:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        14 Àmọ́ Ísírẹ́lì gbé ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ lé orí Éfúrémù bó tiẹ̀ jẹ́ pé òun ni àbúrò, ó sì gbé ọwọ́ òsì rẹ̀ lé orí Mánásè. Ó mọ̀ọ́mọ̀ ṣe bẹ́ẹ̀ ni, torí Mánásè ni àkọ́bí.+ 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Ẹ́kísódù 4:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        22 Kí o sọ fún Fáráò pé, ‘Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ọmọ mi ni Ísírẹ́lì, àkọ́bí mi ni.+ 
 
-