-
Ẹ́sírà 3:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Nítorí náà, àwọn èèyàn ò mọ ìyàtọ̀ nínú igbe ayọ̀ àti igbe ẹkún náà, torí igbe àwọn èèyàn náà ròkè débi pé àwọn tó wà ní ibi tó jìnnà réré ń gbọ́ igbe wọn.
-
-
Sáàmù 126:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
126 Nígbà tí Jèhófà kó àwọn èèyàn Síónì tó wà lóko ẹrú pa dà,+
A rò pé à ń lá àlá ni.
-