Jeremáyà 31:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Nítorí Jèhófà máa ra Jékọ́bù pa dà+Á sì gbà á* lọ́wọ́ ẹni tó lágbára jù ú lọ.+ Sekaráyà 10:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Màá mú wọn pa dà wá láti ilẹ̀ Íjíbítì,Màá sì kó wọn jọ láti Ásíríà;+Màá mú wọn wá sí ilẹ̀ Gílíádì+ àti Lẹ́bánónì,Kò sì ní sí àyè fún wọn.+
10 Màá mú wọn pa dà wá láti ilẹ̀ Íjíbítì,Màá sì kó wọn jọ láti Ásíríà;+Màá mú wọn wá sí ilẹ̀ Gílíádì+ àti Lẹ́bánónì,Kò sì ní sí àyè fún wọn.+