Jeremáyà 29:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “‘Nítorí mo mọ èrò tí mò ń rò nípa yín dáadáa,’ ni Jèhófà wí, ‘èrò àlàáfíà, kì í ṣe ti àjálù,+ láti fún yín ní ọjọ́ ọ̀la kan àti ìrètí kan.+
11 “‘Nítorí mo mọ èrò tí mò ń rò nípa yín dáadáa,’ ni Jèhófà wí, ‘èrò àlàáfíà, kì í ṣe ti àjálù,+ láti fún yín ní ọjọ́ ọ̀la kan àti ìrètí kan.+