-
Àìsáyà 57:5, 6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Tí ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ti kó sí lórí láàárín àwọn igi ńlá,+
Lábẹ́ gbogbo igi tó gbẹ̀rẹ̀gẹ̀jigẹ̀,+
Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń pa àwọn ọmọ ní àwọn àfonífojì,+
Lábẹ́ àwọn pàlàpálá àpáta?
6 Ìpín rẹ wà níbi àwọn òkúta tó jọ̀lọ̀ ní àfonífojì.+
Àní, àwọn ni ìpín rẹ.
Kódà, àwọn lò ń da ọrẹ ohun mímu sí, tí o sì ń mú ẹ̀bùn wá fún.+
Ṣé àwọn nǹkan yìí máa tẹ́ mi lọ́rùn?*
-