Àìsáyà 51:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Àmọ́ èmi ni Jèhófà Ọlọ́run rẹ,Ẹni tó ń ru òkun sókè, tó sì ń mú kí ìgbì rẹ̀ máa pariwo;+Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni orúkọ rẹ̀.+
15 Àmọ́ èmi ni Jèhófà Ọlọ́run rẹ,Ẹni tó ń ru òkun sókè, tó sì ń mú kí ìgbì rẹ̀ máa pariwo;+Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni orúkọ rẹ̀.+