Àìsáyà 63:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Jèhófà, kí ló dé tí o gbà ká* rìn gbéregbère kúrò ní àwọn ọ̀nà rẹ? Kí ló dé tí o gbà kí* ọkàn wa le, tí a ò fi bẹ̀rù rẹ?+ Pa dà, torí àwọn ìránṣẹ́ rẹ,Àwọn ẹ̀yà ogún rẹ.+
17 Jèhófà, kí ló dé tí o gbà ká* rìn gbéregbère kúrò ní àwọn ọ̀nà rẹ? Kí ló dé tí o gbà kí* ọkàn wa le, tí a ò fi bẹ̀rù rẹ?+ Pa dà, torí àwọn ìránṣẹ́ rẹ,Àwọn ẹ̀yà ogún rẹ.+