Sáàmù 102:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Eérú ni mo fi ń ṣe oúnjẹ jẹ,+Omijé sì ti dà pọ̀ mọ́ ohun tí mò ń mu,+ Jeremáyà 6:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ìwọ ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi,Wọ aṣọ ọ̀fọ̀,*+ kí o sì yí nínú eérú. Ṣọ̀fọ̀ bí ẹni tí ọmọkùnrin rẹ̀ kan ṣoṣo kú, kí o sì sunkún gidigidi,+Torí lójijì ni apanirun máa dé bá wa.+
9 Eérú ni mo fi ń ṣe oúnjẹ jẹ,+Omijé sì ti dà pọ̀ mọ́ ohun tí mò ń mu,+ Jeremáyà 6:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ìwọ ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi,Wọ aṣọ ọ̀fọ̀,*+ kí o sì yí nínú eérú. Ṣọ̀fọ̀ bí ẹni tí ọmọkùnrin rẹ̀ kan ṣoṣo kú, kí o sì sunkún gidigidi,+Torí lójijì ni apanirun máa dé bá wa.+
26 Ìwọ ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi,Wọ aṣọ ọ̀fọ̀,*+ kí o sì yí nínú eérú. Ṣọ̀fọ̀ bí ẹni tí ọmọkùnrin rẹ̀ kan ṣoṣo kú, kí o sì sunkún gidigidi,+Torí lójijì ni apanirun máa dé bá wa.+