Ìdárò 2:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Gbogbo ọ̀tá rẹ ti la ẹnu wọn sí ọ. Wọ́n ń súfèé, wọ́n sì wa eyín pọ̀, wọ́n ń sọ pé: “A ti gbé e mì.+ Ọjọ́ tí à ń retí nìyí! + Ó ti dé, a sì ti rí i!”+
16 Gbogbo ọ̀tá rẹ ti la ẹnu wọn sí ọ. Wọ́n ń súfèé, wọ́n sì wa eyín pọ̀, wọ́n ń sọ pé: “A ti gbé e mì.+ Ọjọ́ tí à ń retí nìyí! + Ó ti dé, a sì ti rí i!”+