Jeremáyà 14:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “Sọ ọ̀rọ̀ yìí fún wọn pé,‘Kí omijé ṣàn ní ojú mi tọ̀sántòru, kí ó má sì dá,+Nítorí wọ́n ti lu wúńdíá àwọn èèyàn mi ní àlùbolẹ̀,+Wọ́n sì dá ọgbẹ́ sí i lára yánnayànna. Ìdárò 1:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nítorí nǹkan wọ̀nyí ni mo ṣe ń sunkún;+ omijé sì ń dà lójú mi. Nítorí ẹni tó lè tù mí nínú tàbí tó lè tù mí* lára ti jìnnà réré sí mi. Àwọn ọmọ mi kò nírètí, nítorí ọ̀tá ti borí.
17 “Sọ ọ̀rọ̀ yìí fún wọn pé,‘Kí omijé ṣàn ní ojú mi tọ̀sántòru, kí ó má sì dá,+Nítorí wọ́n ti lu wúńdíá àwọn èèyàn mi ní àlùbolẹ̀,+Wọ́n sì dá ọgbẹ́ sí i lára yánnayànna.
16 Nítorí nǹkan wọ̀nyí ni mo ṣe ń sunkún;+ omijé sì ń dà lójú mi. Nítorí ẹni tó lè tù mí nínú tàbí tó lè tù mí* lára ti jìnnà réré sí mi. Àwọn ọmọ mi kò nírètí, nítorí ọ̀tá ti borí.