ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìdárò 5:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Wọ́n so àwọn ìjòyè rọ̀ ní ọwọ́ wọn,+ wọn kò sì bọ̀wọ̀ fún àwọn àgbààgbà.+

  • Ìsíkíẹ́lì 9:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Ẹ pa àwọn àgbàlagbà ọkùnrin pátápátá àti àwọn géńdé ọkùnrin, wúńdíá, ọmọdé àti àwọn obìnrin.+ Àmọ́ ẹ má ṣe sún mọ́ ẹnikẹ́ni tí àmì náà wà lórí rẹ̀.+ Ibi mímọ́ mi ni kí ẹ ti bẹ̀rẹ̀.”+ Torí náà, wọ́n bẹ̀rẹ̀ látorí àwọn àgbààgbà tí wọ́n wà níwájú ilé náà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́