- 
	                        
            
            Jeremáyà 25:27, 28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        27 “Kí o sì sọ fún wọn pé, ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì, sọ nìyí: “Ẹ mu, kí ẹ sì yó, ẹ bì, kí ẹ sì ṣubú, tí ẹ kò fi ní lè dìde+ nítorí idà tí màá rán sáàárín yín.”’ 28 Bí wọn ò bá sì gba ife náà lọ́wọ́ rẹ láti mu ún, kí o sọ fún wọn pé, ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Ẹ gbọ́dọ̀ mu ún! 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Ọbadáyà 16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        16 Bí o ṣe mu wáìnì lórí òkè mímọ́ mi, Bẹ́ẹ̀ ni gbogbo orílẹ̀-èdè yóò máa mu ìbínú mi nígbà gbogbo.+ Wọn yóò rọ́ ọ sí ọ̀fun, wọn yóò sì gbé e mì, Yóò sì dà bíi pé wọn kò gbé ayé rí. 
 
-