Jeremáyà 13:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nígbà tí o bá sì sọ ní ọkàn rẹ pé, ‘Kí ló dé tí àwọn nǹkan yìí fi ṣẹlẹ̀ sí mi?’+ Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ tó pọ̀ ni wọ́n ṣe ká aṣọ rẹ sókè +Tí wọ́n sì fìyà jẹ gìgísẹ̀ rẹ. Ìsíkíẹ́lì 23:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ìkórìíra ni wọ́n á fi bá ọ jà, wọ́n á kó gbogbo ohun tí o ti ṣe làálàá fún lọ,+ wọ́n á sì fi ọ́ sílẹ̀ ní ìhòòhò. Ìhòòhò rẹ tó ń tini lójú tí o fi ń ṣèṣekúṣe yóò hàn síta, bẹ́ẹ̀ náà ni ìwà àìnítìjú rẹ àti iṣẹ́ aṣẹ́wó rẹ.+
22 Nígbà tí o bá sì sọ ní ọkàn rẹ pé, ‘Kí ló dé tí àwọn nǹkan yìí fi ṣẹlẹ̀ sí mi?’+ Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ tó pọ̀ ni wọ́n ṣe ká aṣọ rẹ sókè +Tí wọ́n sì fìyà jẹ gìgísẹ̀ rẹ.
29 Ìkórìíra ni wọ́n á fi bá ọ jà, wọ́n á kó gbogbo ohun tí o ti ṣe làálàá fún lọ,+ wọ́n á sì fi ọ́ sílẹ̀ ní ìhòòhò. Ìhòòhò rẹ tó ń tini lójú tí o fi ń ṣèṣekúṣe yóò hàn síta, bẹ́ẹ̀ náà ni ìwà àìnítìjú rẹ àti iṣẹ́ aṣẹ́wó rẹ.+