-
Jeremáyà 6:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Ilé wọn máa di ti àwọn ẹlòmíì,
Títí kan àwọn oko wọn àti ìyàwó wọn.+
Torí màá na ọwọ́ mi sí àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà,” ni Jèhófà wí.
-