Sáàmù 79:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Jèhófà, ìgbà wo lo máa bínú dà? Ṣé títí láé ni?+ Ìgbà wo ni ìbínú ńlá rẹ máa jó bí iná dà?+ Jeremáyà 14:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ṣé o kọ Júdà sílẹ̀ pátápátá ni, àbí o* ti kórìíra Síónì dé góńgó ni?+ Kí nìdí tí o fi lù wá débi tí a ò fi lè rí ìwòsàn?+ À ń retí àlàáfíà, àmọ́ ohun rere kan ò dé,À ń retí àkókò ìwòsàn, àmọ́ ìpayà là ń rí!+
19 Ṣé o kọ Júdà sílẹ̀ pátápátá ni, àbí o* ti kórìíra Síónì dé góńgó ni?+ Kí nìdí tí o fi lù wá débi tí a ò fi lè rí ìwòsàn?+ À ń retí àlàáfíà, àmọ́ ohun rere kan ò dé,À ń retí àkókò ìwòsàn, àmọ́ ìpayà là ń rí!+