-
Diutarónómì 4:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Tí wàhálà tó le gan-an bá dé bá ọ, tí gbogbo nǹkan yìí sì wá ṣẹlẹ̀ sí ọ, wàá pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run rẹ, wàá sì fetí sí ohùn rẹ̀.+
-
-
Jeremáyà 31:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 “Mo ti gbọ́ tí Éfúrémù ń kérora,
‘O ti tọ́ mi sọ́nà, mo sì ti gba ìtọ́sọ́nà,
Bí ọmọ màlúù tí a kò fi iṣẹ́ kọ́.
Mú mi pa dà, màá sì ṣe tán láti yí pa dà,
Nítorí ìwọ ni Jèhófà Ọlọ́run mi.
-