-
Léfítíkù 26:37Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
37 Wọ́n á kọ lu ara wọn bí ẹni ń sá fún idà, bó tiẹ̀ jẹ́ pé kò sẹ́ni tó ń lé wọn. Ẹ ò ní lè kojú àwọn ọ̀tá yín.+
-
-
Ìsíkíẹ́lì 11:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 ‘Èmi yóò mú yín jáde kúrò nínú rẹ̀, màá mú kí ọwọ́ àwọn àjèjì tẹ̀ yín, màá sì dá yín lẹ́jọ́.+
-