2 Àwọn Ọba 25:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ọba Bábílónì ṣá wọn balẹ̀, ó sì pa wọ́n ní Ríbúlà ní ilẹ̀ Hámátì.+ Bí Júdà ṣe lọ sí ìgbèkùn láti ilẹ̀ rẹ̀ nìyẹn.+
21 Ọba Bábílónì ṣá wọn balẹ̀, ó sì pa wọ́n ní Ríbúlà ní ilẹ̀ Hámátì.+ Bí Júdà ṣe lọ sí ìgbèkùn láti ilẹ̀ rẹ̀ nìyẹn.+