Jeremáyà 52:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Olórí ẹ̀ṣọ́ tún mú Seráyà+ olórí àlùfáà àti Sefanáyà+ àlùfáà kejì pẹ̀lú àwọn aṣọ́nà mẹ́ta.+ Jeremáyà 52:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ọba Bábílónì ṣá wọn balẹ̀, ó sì pa wọ́n ní Ríbúlà+ ní ilẹ̀ Hámátì. Bí Júdà ṣe lọ sí ìgbèkùn láti ilẹ̀ rẹ̀ nìyẹn.+
27 Ọba Bábílónì ṣá wọn balẹ̀, ó sì pa wọ́n ní Ríbúlà+ ní ilẹ̀ Hámátì. Bí Júdà ṣe lọ sí ìgbèkùn láti ilẹ̀ rẹ̀ nìyẹn.+