-
Ìsíkíẹ́lì 9:6, 7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ẹ pa àwọn àgbàlagbà ọkùnrin pátápátá àti àwọn géńdé ọkùnrin, wúńdíá, ọmọdé àti àwọn obìnrin.+ Àmọ́ ẹ má ṣe sún mọ́ ẹnikẹ́ni tí àmì náà wà lórí rẹ̀.+ Ibi mímọ́ mi ni kí ẹ ti bẹ̀rẹ̀.”+ Torí náà, wọ́n bẹ̀rẹ̀ látorí àwọn àgbààgbà tí wọ́n wà níwájú ilé náà.+ 7 Lẹ́yìn náà, ó sọ fún wọn pé: “Ẹ sọ ilé náà di ẹlẹ́gbin, kí ẹ sì fi òkú èèyàn kún inú àwọn àgbàlá.+ Ẹ lọ!” Ni wọ́n bá lọ, wọ́n sì pa àwọn èèyàn ní ìlú náà.
-