Ìdárò 4:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Máa yọ̀ kí inú rẹ sì máa dùn, ìwọ ọmọbìnrin Édómù,+ bí o ṣe ń gbé ní ilẹ̀ Úsì. Àmọ́ wọ́n á gbé ife náà fún ìwọ pẹ̀lú,+ wàá mu àmupara, wàá sì tú ara rẹ sí ìhòòhò.+ Ọbadáyà 12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Kò yẹ kí o fi ọmọ ìyá rẹ ṣe yẹ̀yẹ́ ní ọjọ́ tí àjálù bá a,+Kò yẹ kí o yọ̀ lórí àwọn ọmọ Júdà ní ọjọ́ tí wọ́n ń ṣègbé lọ,+Kò sì yẹ kí o máa fọ́nnu ní ọjọ́ wàhálà wọn. Ọbadáyà 15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Nítorí ọjọ́ tí Jèhófà fẹ́ bá gbogbo orílẹ̀-èdè jà ti sún mọ́lé.+ Ohun tí o ṣe ni wọn yóò ṣe sí ọ.+ Ìwà tí o hù sí àwọn èèyàn ni wọn yóò hù sí ọ.
21 Máa yọ̀ kí inú rẹ sì máa dùn, ìwọ ọmọbìnrin Édómù,+ bí o ṣe ń gbé ní ilẹ̀ Úsì. Àmọ́ wọ́n á gbé ife náà fún ìwọ pẹ̀lú,+ wàá mu àmupara, wàá sì tú ara rẹ sí ìhòòhò.+
12 Kò yẹ kí o fi ọmọ ìyá rẹ ṣe yẹ̀yẹ́ ní ọjọ́ tí àjálù bá a,+Kò yẹ kí o yọ̀ lórí àwọn ọmọ Júdà ní ọjọ́ tí wọ́n ń ṣègbé lọ,+Kò sì yẹ kí o máa fọ́nnu ní ọjọ́ wàhálà wọn.
15 Nítorí ọjọ́ tí Jèhófà fẹ́ bá gbogbo orílẹ̀-èdè jà ti sún mọ́lé.+ Ohun tí o ṣe ni wọn yóò ṣe sí ọ.+ Ìwà tí o hù sí àwọn èèyàn ni wọn yóò hù sí ọ.