-
Àìsáyà 52:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 “Kí wá ni kí n ṣe níbí?” ni Jèhófà wí.
“Ọ̀fẹ́ ni wọ́n kó àwọn èèyàn mi lọ.
-
-
Róòmù 2:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Torí “àwọn èèyàn ń sọ̀rọ̀ òdì sí orúkọ Ọlọ́run láàárín àwọn orílẹ̀-èdè nítorí yín,” bó ṣe wà lákọsílẹ̀.+
-