Sáàmù 106:7, 8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àwọn baba ńlá wa ní Íjíbítì kò mọyì* àwọn iṣẹ́ àgbàyanu rẹ. Wọn ò rántí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ tó pọ̀ gidigidi,Wọ́n ṣọ̀tẹ̀ ní òkun, létí Òkun Pupa.+ 8 Àmọ́, ó gbà wọ́n sílẹ̀ nítorí orúkọ rẹ̀,+Kí wọ́n lè mọ bí agbára rẹ̀ ṣe pọ̀ tó.+
7 Àwọn baba ńlá wa ní Íjíbítì kò mọyì* àwọn iṣẹ́ àgbàyanu rẹ. Wọn ò rántí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ tó pọ̀ gidigidi,Wọ́n ṣọ̀tẹ̀ ní òkun, létí Òkun Pupa.+ 8 Àmọ́, ó gbà wọ́n sílẹ̀ nítorí orúkọ rẹ̀,+Kí wọ́n lè mọ bí agbára rẹ̀ ṣe pọ̀ tó.+